Jeremaya 27:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní òun ti fún Nebukadinesari, ọba Babiloni iranṣẹ òun, ní gbogbo àwọn ilẹ̀ wọnyi, òun sì ti fún un ni àwọn ẹranko inú igbó kí wọn máa ṣe iranṣẹ rẹ̀.

Jeremaya 27

Jeremaya 27:1-16