Jeremaya 27:22 BIBELI MIMỌ (BM)

wọn óo kó lọ sí Babiloni, níbẹ̀ ni wọn yóo sì wà títí di ọjọ́ tí mo bá ranti wọn. N óo wá kó wọn pada wá sí ibí yìí nígbà náà.”

Jeremaya 27

Jeremaya 27:20-22