Jeremaya 27:20 BIBELI MIMỌ (BM)

tí Nebukadinesari, ọba Babiloni, kò kó lọ, nígbà tí ó kó Jehoiakini, ọba Juda, ọmọ Jehoiakimu, ati gbogbo àwọn ọlọ́lá Juda ati ti Jerusalẹmu lọ sí Babiloni.

Jeremaya 27

Jeremaya 27:18-22