Jeremaya 27:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ wọn. Ẹ sin ọba Babiloni, kí ẹ lè wà láàyè. Kí ló dé tí ìlú yìí yóo fi di ahoro?

Jeremaya 27

Jeremaya 27:10-20