Jeremaya 27:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ àwọn wolii tí wọn ń wí fun yín pé ẹ kò ní ṣe ẹrú ọba Babiloni, nítorí pé àsọtẹ́lẹ̀ èké ni wọ́n ń sọ fun yín.

Jeremaya 27

Jeremaya 27:6-22