Jeremaya 27:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣẹ́ yìí kan náà ni mo jẹ́ fún Sedekaya ọba Juda. Mo ní, “Fi ọrùn rẹ sinu àjàgà ọba Babiloni, kí o sin òun ati àwọn eniyan rẹ̀, kí o lè wà láàyè.

Jeremaya 27

Jeremaya 27:7-18