Jeremaya 27:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àsọtẹ́lẹ̀ èké ni wọ́n ń sọ fun yín, wọ́n fẹ́ kí á ko yín jìnnà sí ilẹ̀ yín ni. N óo le yín jáde; ẹ óo sì ṣègbé.

Jeremaya 27

Jeremaya 27:7-14