Jeremaya 26:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya bá sọ fún àwọn ìjòyè ati gbogbo àwọn eniyan pé, “OLUWA ni ó rán mi láti sọ àsọtẹ́lẹ̀ tí ẹ gbọ́ sí ilé yìí ati ìlú yìí.

Jeremaya 26

Jeremaya 26:11-21