Jeremaya 25:24 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún gbogbo àwọn ọba Arabia mu ati gbogbo àwọn ọba oríṣìíríṣìí ẹ̀yà tí wọn ń gbé aṣálẹ̀.

Jeremaya 25

Jeremaya 25:21-25