Jeremaya 25:19 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún Farao, ọba Ijipti mu, ati àwọn iranṣẹ rẹ̀ ati àwọn ìjòyè rẹ̀, ati gbogbo àwọn eniyan rẹ̀

Jeremaya 25

Jeremaya 25:12-20