Jeremaya 25:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ilẹ̀ yìí yóo di àlàpà ati aṣálẹ̀. Àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi yóo sì sin ọba Babiloni fún aadọrin ọdún.

Jeremaya 25

Jeremaya 25:10-14