Jeremaya 24:7 BIBELI MIMỌ (BM)

n óo sì fún wọn ní òye láti mọ̀ pé èmi ni OLUWA. Wọn yóo jẹ́ eniyan mi, èmi náà óo sì jẹ́ Ọlọrun wọn; nítorí tí wọn yóo fi tọkàntọkàn yipada sí mi.”

Jeremaya 24

Jeremaya 24:2-10