Jeremaya 24:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní òun óo rán ogun, ìyàn ati àjàkálẹ̀ àrùn sí wọn, títí wọn yóo fi kú tán, tí kò ní ku ẹyọ ẹnìkan lórí ilẹ̀ tí òun fún àwọn ati àwọn baba ńlá wọn.

Jeremaya 24

Jeremaya 24:6-10