Jeremaya 23:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wolii kan tabi alufaa kan tabi ẹnikẹ́ni ninu àwọn eniyan wọnyi bá wí pé òun ń jẹ́ iṣẹ́ OLUWA, n óo jẹ olúwarẹ̀ ati ilé rẹ̀ níyà.

Jeremaya 23

Jeremaya 23:32-37