Jeremaya 23:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo lòdì sí àwọn wolii tí wọn ń sọ ọ̀rọ̀ ti ara wọn, tí wọn ń sọ pé èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Jeremaya 23

Jeremaya 23:21-32