Jeremaya 23:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí bí iná ni ọ̀rọ̀ mi rí, ati bí òòlù irin tíí fọ́ àpáta sí wẹ́wẹ́?

Jeremaya 23

Jeremaya 23:21-37