Jeremaya 22:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo sì máa dáhùn pé, ‘Nítorí pé wọ́n kọ majẹmu OLUWA Ọlọrun wọn sílẹ̀ ni, wọ́n ń bọ oriṣa, wọ́n sì ń sìn wọ́n.’ ”

Jeremaya 22

Jeremaya 22:3-13