Jeremaya 22:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ kọ orúkọ ọkunrin yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aláìlọ́mọ,ẹni tí kò ní ṣe rere kan ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀;nítorí pé kò sí ọ̀kankan ninu àwọn ọmọ rẹ̀tí yóo rọ́pò rẹ̀ lórí ìtẹ́ Dafidi,Ìdílé rẹ̀ kò sì ní jọba mọ ní Juda.”

Jeremaya 22

Jeremaya 22:26-30