Jeremaya 22:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ilé kedari tí o kọ́ ni ó sọ ọ́ di ọba?Wo baba rẹ, ṣé kò rí jẹ ni,tabi kò rí mu?Ṣebí ó ṣe ẹ̀tọ́ ati òdodo,ṣebí ó sì dára fún un.

Jeremaya 22

Jeremaya 22:6-19