Jeremaya 22:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó ń fi aiṣododo kọ́ ilé rẹ̀ gbé,tí ó ń fi ọ̀nà èrú kọ́ òrùlé rẹ̀.Tí ó mú ọmọ ẹnìkejì rẹ̀ sìn lọ́fẹ̀ẹ́,láìsan owó iṣẹ́ rẹ̀ fún un.

Jeremaya 22

Jeremaya 22:12-22