Jeremaya 21:14 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo jẹ yín níyà gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ yín;èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.N óo dáná sun igbó yín,yóo sì jó gbogbo ohun tí ó wà ní agbègbè yín ní àjórun.”

Jeremaya 21

Jeremaya 21:8-14