Jeremaya 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ tí Jeremaya gbọ́ lẹ́nu OLUWA nìyí nígbà tí ọba Sedekaya rán Paṣuri, ọmọ Malikaya, ati alufaa Sefanaya, ọmọ Maaseaya, sí i;

Jeremaya 21

Jeremaya 21:1-9