Jeremaya 20:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Paṣuri alufaa, ọmọ Imeri, tí ó jẹ́ olórí àwọn olùṣọ́ ilé OLUWA, gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremaya ń sọ,

Jeremaya 20

Jeremaya 20:1-6