Jeremaya 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹ mo gbìn yín gẹ́gẹ́ bí àjàrà tí mo fẹ́,tí èso rẹ̀ dára.Báwo ni ẹ ṣe wá yipada patapata,tí ẹ di àjàrà igbó tí kò wúlò?

Jeremaya 2

Jeremaya 2:20-30