Jeremaya 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí ọwọ́ ara yín ni ẹ fi fà á sí orí ara yín,nígbà tí ẹ̀yin kọ Ọlọrun yín sílẹ̀,nígbà tí ó ń tọ yín sọ́nà?

Jeremaya 2

Jeremaya 2:15-25