Jeremaya 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ọjọ́ ń bọ̀, tí a kò ní pe ibí yìí ní Tofeti tabi àfonífojì ọmọ Hinomu mọ́. Àfonífojì ìpànìyàn ni a óo máa pè é.

Jeremaya 19

Jeremaya 19:5-13