Jeremaya 19:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe sí ìlú yìí ati àwọn tí wọn ń gbé ibẹ̀. Bíi Tofeti ni n óo ṣe ìlú náà; Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Jeremaya 19

Jeremaya 19:4-13