Kí igbe ẹkún ó sọ ninu ilé wọn,nígbà tí o bá mú àwọn apanirun wá sórí wọn lójijì;nítorí pé wọ́n wa kòtò láti mú mi,wọ́n dẹ tàkúté sílẹ̀ fún mi.