Jeremaya 18:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé yìnyín òkè Lẹbanoni a máa dà ní pàlàpálá Sirioni?Àbí omi tútù tí máa ń ṣàn láti inú òkè rẹ̀ a máa gbẹ?

Jeremaya 18

Jeremaya 18:7-17