Jeremaya 17:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní kí ẹ ṣọ́ra fún ẹ̀mí yín, ẹ má máa ru ẹrù ní ọjọ́ ìsinmi, ẹ má gbé ẹrù wọ ẹnubodè Jerusalẹmu ní ọjọ́ ìsinmi mọ́.

Jeremaya 17

Jeremaya 17:15-24