Jeremaya 17:19 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ fún mi pé, “Lọ dúró ní ẹnubodè Bẹnjamini níbí, tí àwọn ọba Juda máa ń gbà wọlé, tí wọn sìí gbà jáde; ati ní gbogbo ẹnubodè Jerusalẹmu,

Jeremaya 17

Jeremaya 17:10-27