Jeremaya 17:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò mí sàn, OLUWA, ara mi yóo sì dá,gbà mí, n óo sì bọ́ ninu ewu.Nítorí pé ìwọ ni mò ń yìn.

Jeremaya 17

Jeremaya 17:7-15