Jeremaya 16:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé mò ń wo gbogbo ohun tí wọn ń ṣe, kò sí èyí tí n kò rí, bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀ṣẹ̀ wọn kò sápamọ́ fún mi.

Jeremaya 16

Jeremaya 16:11-21