Jeremaya 15:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Ẹ̀yin ará Jerusalẹmu, ta ni yóo ṣàánú yín?Ta ni yóo dárò yín?Ta ni yóo ya ọ̀dọ̀ yín, láti bèèrè alaafia yín?

Jeremaya 15

Jeremaya 15:1-10