Jeremaya 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Oríṣìí ìparun mẹrin ni n óo jẹ́ kí ó dé bá wọn: idà óo pa wọ́n, ajá óo fà wọ́n ya, àwọn ẹyẹ ati àwọn ẹranko óo jẹ wọ́n ní àjẹrun.

Jeremaya 15

Jeremaya 15:1-8