Jeremaya 15:17 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò jókòó láàrin àwọn alárìíyá, bẹ́ẹ̀ ni n kò yọ̀. Mo dá jókòó nítorí àṣẹ rẹ, nítorí o ti fi ìrúnú kún ọkàn mi.

Jeremaya 15

Jeremaya 15:12-19