Jeremaya 14:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó dúró lórí òkè,wọ́n ń mí hẹlẹhẹlẹ bí ajáko.Ojú wọn rẹ̀wẹ̀sì, nítorí kò sí koríko.

Jeremaya 14

Jeremaya 14:5-11