Jeremaya 14:17 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fun mi pé, “Sọ fún wọn pé,‘Kí omijé máa ṣàn lójú mi tọ̀sán-tòru,kí ó má dáwọ́ dúró,nítorí ọgbẹ́ ńlá tí a fi tagbára tagbára ṣá eniyan mi.

Jeremaya 14

Jeremaya 14:10-19