Jeremaya 13:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọpọlọpọ ọjọ́, OLUWA sọ fún mi pé, “Dìde, lọ sí odò Yufurate kí o mú aṣọ tí mo ní kí o fi pamọ́ sibẹ wá.”

Jeremaya 13

Jeremaya 13:1-14