Jeremaya 13:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni ìpín yín,ìpín tí mo ti yàn fun yín,nítorí pé ẹ ti gbàgbé èmi OLUWA, ẹ sì gbẹ́kẹ̀lé ọlọrun èké.

Jeremaya 13

Jeremaya 13:24-27