Jeremaya 13:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Wí fún ọba ati ìyá ọba pé,“Ẹ sọ̀kalẹ̀ lórí ìtẹ́ yín,nítorí adé yín tí ó lẹ́wà ti ṣí bọ́ sílẹ̀ lórí yín.”

Jeremaya 13

Jeremaya 13:10-21