Jeremaya 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

O gbìn wọ́n, wọ́n ta gbòǹgbò;wọ́n dàgbà, wọ́n so èso;orúkọ rẹ kò jìnnà sẹ́nu wọn,ṣugbọn ọkàn wọn jìnnà sí ọ.

Jeremaya 12

Jeremaya 12:1-7