Jeremaya 12:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí orílẹ̀-èdè kan bá ṣe àìgbọràn, n óo yọ ọ́ kúrò patapata, n óo sì pa á run. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Jeremaya 12

Jeremaya 12:7-17