Jeremaya 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí mo bá kó wọn kúrò tán, n óo pada ṣàánú wọn, n óo dá olukuluku pada sí ilẹ̀ ìní rẹ̀.

Jeremaya 12

Jeremaya 12:5-17