Jeremaya 10:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́ àhesọ ọ̀rọ̀ kan! Ó ń tàn kálẹ̀!Ìdàrúdàpọ̀ ńlá ń bọ̀ láti ilẹ̀ àríwá,tí yóo sọ àwọn ìlú Juda di ahoroyóo sì di ibùgbé àwọn ajáko.

Jeremaya 10

Jeremaya 10:12-25