Jeremaya 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ni ó fi agbára rẹ̀ dá ayé,tí ó fi ọgbọ́n fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ sọlẹ̀,tí ó sì fi òye rẹ̀ ta ojú ọ̀run bí aṣọ.

Jeremaya 10

Jeremaya 10:11-16