Jeremaya 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kí n tó dá ọ sinu ìyá rẹ ni mo ti mọ̀ ọ́,kí wọ́n sì tó bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀,mo yàn ọ́ ní wolii fún àwọn orílẹ̀-èdè.”

Jeremaya 1

Jeremaya 1:1-12