Jeremaya 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà ayé Josaya, ọmọ Amoni, ọba Juda, ní ọdún kẹtala tí Josaya gun orí oyè ni OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀.

Jeremaya 1

Jeremaya 1:1-6