Jeremaya 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá wí fún mi pé, “Òtítọ́ ni ohun tí o rí, nítorí mò ń sọ ọ̀rọ̀ tí mo sọ, n óo sì mú un ṣẹ.”

Jeremaya 1

Jeremaya 1:9-19