Jẹnẹsisi 9:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí òṣùmàrè bá yọ, n óo wò ó, n óo sì ranti majẹmu ayérayé tí èmi Ọlọrun bá gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ó wà láyé dá.

Jẹnẹsisi 9

Jẹnẹsisi 9:10-19